2 Ọba 6:9 BMY

9 Ènìyàn Ọlọ́run rán iṣẹ́ sí ọba Ísírẹ́lì, “kíyèsí ara láti kọjá ní ibẹ̀ yẹn, nítorí pé ará Árámù wọ́n sọ̀kalẹ̀ lọ síbẹ̀.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 6

Wo 2 Ọba 6:9 ni o tọ