2 Ọba 8:3 BMY

3 Ní ẹ̀yìn ọdún méje ó sì padà wá láti ilẹ̀ àwọn ará Fílístínì ó sì lọ sí ọ̀dọ̀ ọba láti lọ bẹ̀ẹ́ fún ilé àti ilẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 8

Wo 2 Ọba 8:3 ni o tọ