2 Ọba 9:24 BMY

24 Nígbà náà, Jéhù fa ọrun rẹ̀, ó sì yin Jórámù láàárin èjìká méjèèjì. Ọfà náà sì wọ inú ọkàn rẹ̀, ó sì ṣubú lulẹ̀ láti orí kẹ̀kẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 9

Wo 2 Ọba 9:24 ni o tọ