2 Ọba 9:30 BMY

30 Nígbà náà Jéhù lọ sí Jésérẹ́lì. Nígbà tí Jésébélì gbọ́ nípa rẹ̀, ó kun ojú u rẹ̀, ó to irun rẹ̀, ó sì wò jáde láti ojú fèrèsé.

Ka pipe ipin 2 Ọba 9

Wo 2 Ọba 9:30 ni o tọ