2 Ọba 9:34 BMY

34 Jéhù wọ inú ilé lọ, ó jẹ ó sì mu. “Tọ́jú obìnrin yẹn tí a fi bú,” Ó wí, “Kí o sì sin-ín, nítorí ọmọbìnrin ọba ni ó jẹ́.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 9

Wo 2 Ọba 9:34 ni o tọ