2 Ọba 9:9 BMY

9 Èmi yóò ṣe ilé Áhábù gẹ́gẹ́ bí ilé Jéróbóhámù ọmọ Nábátì àti ilé Bááṣà ọmọ Áhíjà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 9

Wo 2 Ọba 9:9 ni o tọ