2 Sámúẹ́lì 1:16 BMY

16 Nítorí Dáfídì wí fún un pé, “Ẹ̀jẹ̀ rẹ yóò wà lórí ara rẹ, nítorí ẹnu ara rẹ ni o fi sọ pé ‘Mo pa ẹni àmì òróró Olúwa.’ ”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 1

Wo 2 Sámúẹ́lì 1:16 ni o tọ