2 Sámúẹ́lì 11:24 BMY

24 Àwọn tafàtafà sì ta sí ìránṣẹ́ rẹ láti orí odi wá, díẹ̀ nínú àwọn ìránṣẹ́ ọba sì kú, ìránṣẹ́ rẹ̀ Ùráyà ará Hítì sì kú pẹ̀lú.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 11

Wo 2 Sámúẹ́lì 11:24 ni o tọ