25 Ọba sì wí fún Sádókù pé, “Sì tún gbé àpótí-ẹ̀rí Ọlọ́run náà padà sí ìlú: bí èmi bá rí ojú rere gbà lọ́dọ̀ Olúwa, yóò sì tún mú mi padà wá, yóò sì fi àpótí-ẹ̀rí náà hàn mí àti ibùgbé rẹ̀.
Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 15
Wo 2 Sámúẹ́lì 15:25 ni o tọ