2 Sámúẹ́lì 16:22 BMY

22 Wọ́n sì tẹ́ àgọ́ kan fún Ábúsálómù ní òrùlé; Ábúsálómù sì wọlé tọ àwọn obìnrin baba rẹ̀ lójú gbogbo Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 16

Wo 2 Sámúẹ́lì 16:22 ni o tọ