2 Sámúẹ́lì 16:23 BMY

23 Ìmọ̀ Áhítófélì tí ó máa ń gbà ni ìgbà náà, ó dàbí ẹni pé ènìyàn béèrè nǹkan lọ́wọ́ Ọlọ́run: bẹ́ẹ̀ ni gbogbo ìmọ̀ Áhítófélì fún Dáfídì àti fún Ábúsálómù sì rí.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 16

Wo 2 Sámúẹ́lì 16:23 ni o tọ