2 Sámúẹ́lì 18:24 BMY

24 Dáfídì sì jókòó lẹ́nu odì láàrin ìlẹ̀kùn méjì: Álóre sì gòkè òrùlé bodè lórí odi, ó sì gbé ojú rẹ̀ sókè, ó sì wò, wò ó, ọkùnrin kan ń sáré òun nìkan.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 18

Wo 2 Sámúẹ́lì 18:24 ni o tọ