2 Sámúẹ́lì 18:25 BMY

25 Álóre náà sì kígbe, ó sì wí fún ọba.Ọba sì wí pé, “Bí ó bá ṣe òun nìkan ni, ìhìn rere ń bẹ lẹ́nu rẹ̀.” Òun sì ń súnmọ́ tòsí.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 18

Wo 2 Sámúẹ́lì 18:25 ni o tọ