2 Sámúẹ́lì 18:4 BMY

4 Ọba sì wí fún wọn pé, “Èyí tí ó bá tọ́ lójú yin ni èmi ó ṣe.”Ọba sì dúró ní apákan ẹnu odi, gbogbo àwọn ènìyàn náà sì jáde ní ọrọrún àti ní ẹgbẹẹgbẹ̀rún.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 18

Wo 2 Sámúẹ́lì 18:4 ni o tọ