2 Sámúẹ́lì 2:24 BMY

24 Jóábù àti Ábíṣáì sì lépa Ábínérì: òòrùn sì wọ̀, wọ́n sì dé òkè ti Ámímà tí o wà níwájú Gíà lọ́nà ijù Gíbíónì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 2

Wo 2 Sámúẹ́lì 2:24 ni o tọ