2 Sámúẹ́lì 20:22 BMY

22 Obìnrin náà sì mú ìmọ́ran rẹ̀ tọ gbogbo àwọn ènìyàn náà, wọ́n sì bẹ Ṣébà ọmọ Bíkírì lórí, wọ́n sì sọ ọ́ sí Jóábù. Òun sì fún ìpè, wọ́n sì túká sọ́dọ̀ ọba.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 20

Wo 2 Sámúẹ́lì 20:22 ni o tọ