2 Sámúẹ́lì 20:23 BMY

23 Jóábù sì ni olórí gbogbo ogun Ísírẹ́lì: Bénáyà ọmọ Jéhóiádà sì jẹ́ olórí àwọn Kérétì, àti ti àwọn Pélétì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 20

Wo 2 Sámúẹ́lì 20:23 ni o tọ