2 Sámúẹ́lì 22:1 BMY

1 Dáfídì sì kọ ọ̀rọ̀ orin yìí sí Olúwa ní ọjọ́ tí Olúwa gbà á kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀ta rẹ̀, àti kúrò lọ́wọ́ Sọ́ọ̀lù.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 22

Wo 2 Sámúẹ́lì 22:1 ni o tọ