2 Sámúẹ́lì 23:7 BMY

7 Ṣùgbọ́n ọkùnrin tí yóò tọ́ wọn yóòfi irin àti ọ̀pá ọ̀kọ̀ ṣagbára yí ara rẹ̀ ká;wọn ó Jóná lúúlú níbì kan náà.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 23

Wo 2 Sámúẹ́lì 23:7 ni o tọ