2 Sámúẹ́lì 24:11 BMY

11 Dáfídì sì dìde ní òwúrọ̀, ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ Gádì wòlíì wá, aríran Dáfídì wí pé:

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:11 ni o tọ