2 Sámúẹ́lì 24:12 BMY

12 “Lọ kí o sì wí fún Dáfídì pé, ‘Bàyìí ni Olúwa wí, èmi fi nǹkan mẹ́ta lọ̀ ọ́; yan ọ̀kan nínú wọn, kí èmi ó sì ṣe é sí ọ.’ ”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:12 ni o tọ