2 Sámúẹ́lì 24:24 BMY

24 Ọba sì wí fún Áráúnà pé, “Bẹ́ẹ̀ kọ́; ṣùgbọ́n èmi ó rà á ní iye kan lọ́wọ́ rẹ, bí ó ti wù kí ó ṣe; bẹ́ẹ̀ ni èmi kì yóò fi èyí tí èmi kò náwó fún, rú ẹbọ sísun sí Olúwa Ọlọ́run mi.”Dáfídì sì ra ibi ìpakà náà, àti àwọn màlúù náà ní àádọ́ta sékélì fàdákà.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:24 ni o tọ