2 Sámúẹ́lì 24:25 BMY

25 Dáfídì sì tẹ́ pẹpẹ kan níbẹ̀ sí Olúwa, ó sì rú ẹbọ sísun àti ti ìlàjà. Olúwa sì gbọ́ ẹ̀bẹ̀ fún ilẹ̀ náà, àrùn náà sì dá kúrò ní Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:25 ni o tọ