2 Sámúẹ́lì 24:4 BMY

4 Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ ọba borí ti Jóábù, àti ti àwọn olórí ogun. Jóábù àti àwọn olórí ogun sì jáde lọ kúrò níwájú ọba, láti lọ ka àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:4 ni o tọ