2 Sámúẹ́lì 24:5 BMY

5 Wọ́n sì kọjá odò Jọ́dánì, wọ́n sì pàgọ́ ní Áróérì, ní ìhà apá ọtún ìlú tí ó wà láàrin àfonífojì Gádì, àti sí ìhà Jásérì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:5 ni o tọ