2 Sámúẹ́lì 4:10 BMY

10 Nígbà tí ẹnìkan rò fún mi pé, ‘Wò ó, Ṣọ́ọ̀lù ti kú,’ lójú ara rẹ̀ òun sì jásí ẹni tí ó mú ìhìnrere wá, èmi sì mú un, mo sì pa á ní Síkílágì, ẹni tí ó ṣebí òun ó rí nǹkan gbà nítorí ìhìn rere rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 4

Wo 2 Sámúẹ́lì 4:10 ni o tọ