2 Sámúẹ́lì 4:11 BMY

11 Mélòó mélòó ni, nígbà tí àwọn ìká ènìyàn pa olódodo ènìyàn kan ni ilé rẹ̀ lórí ibùsùn rẹ̀—ǹjẹ́ èmi ha sì lè ṣe aláìbéèrè ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ yín bí? Kí èmi sì mú yín kúrò láàyè.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 4

Wo 2 Sámúẹ́lì 4:11 ni o tọ