2 Sámúẹ́lì 4:4 BMY

4 (Jónátanì ọmọ Ṣọ́ọ̀lù sì ti bí ọmọkùnrin kan tí ẹsẹ̀ rẹ̀ rọ, òun sì jẹ́ ọdún márùn-ún, nígbà tí ìhìn dé ní ti Ṣọ́ọ̀lù àti Jónátanì láti Jésírẹẹlì wá, olùtọ́ rẹ̀ sì gbé e, o sì sá lọ, ó sì ṣe, bí ó sì ti ń yára láti sá lọ, òun sì ṣubú, ó sì ya arọ. Orúkọ rẹ̀ a máa jẹ́ Méfíbóṣétì.)

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 4

Wo 2 Sámúẹ́lì 4:4 ni o tọ