2 Sámúẹ́lì 4:5 BMY

5 Àwọn ọmọ Rímímónì, ará Béérótì, Rákábù àti Báánà sì lọ wọ́n sì wá sí ilé Iṣíbóṣétì ní ọsán gangan, òun sì sinmi lórí ibùsùn kan ní ọjọ́ kan-rí.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 4

Wo 2 Sámúẹ́lì 4:5 ni o tọ