2 Sámúẹ́lì 4:7 BMY

7 Nígbà tí wọ́n wọ ilé náà lọ, òun sì dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ̀ nínú iyàrá rẹ̀, wọ́n sì pa á, wọ́n sì bẹ́ ẹ lórí, wọ́n gbé orí sá lọ, wọ́n sì fi gbogbo òru rìn ni pẹ̀tẹ́lẹ̀ náà.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 4

Wo 2 Sámúẹ́lì 4:7 ni o tọ