2 Sámúẹ́lì 6:6 BMY

6 Nígbà tí wọ́n sì dé ibi ìpakà Nákónì, Úsà sì na ọwọ́ rẹ̀ sí àpótí-ẹ̀rí Ọlọ́run, ó sì dì í mú, nítorí tí màlúù kọsẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 6

Wo 2 Sámúẹ́lì 6:6 ni o tọ