2 Sámúẹ́lì 6:7 BMY

7 Ibínú Olúwa sì ru sí Úsà; Ọlọ́run sì pa á níbẹ̀ nítorí ìṣìṣe rẹ̀; níbẹ̀ ni ó sì kù ní ẹ̀bá àpótí-ẹ̀rí Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 6

Wo 2 Sámúẹ́lì 6:7 ni o tọ