2 Sámúẹ́lì 7:1 BMY

1 Ó sì ṣe, nígbà tí ọba ń gbé ní ilé rẹ̀, tí Olúwa sì fún un ní ìsinmi yíká kiri kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 7

Wo 2 Sámúẹ́lì 7:1 ni o tọ