2 Sámúẹ́lì 7:2 BMY

2 Ọba sì wí fún Nátánì wòlíì pé, “Sá wò ó: èmi ń gbé inú ilẹ̀ tí a fi kédárì kọ́, ṣùgbọ́n àpótí-ẹ̀rí Ọlọ́run ń gbé inú ibi tí a fi aṣọ gé.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 7

Wo 2 Sámúẹ́lì 7:2 ni o tọ