2 Sámúẹ́lì 7:18 BMY

18 Dáfídì ọba sì wọlé lọ, ó sì dúró níwájú Olúwa, ó sì wí pé:“Olúwa Ọlọ́run, ta ni èmi, àti kí sì ni ìdílé mi, tí ìwọ fi mú mi di ìsinsin yìí?

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 7

Wo 2 Sámúẹ́lì 7:18 ni o tọ