2 Sámúẹ́lì 7:19 BMY

19 Nǹkan kékeré ni èyí sáà jásí lójú rẹ, Olúwa Ọlọ́run; ìwọ sì ti sọ nípa ìdílé ìránṣẹ́ rẹ pẹ̀lú ní ti àkókò tí o jìnnà. Èyí há ṣe ìwà ènìyàn bí, Olúwa Ọlọ́run?

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 7

Wo 2 Sámúẹ́lì 7:19 ni o tọ