24 Ìwọ sì fi ìdí àwọn ènìyàn rẹ, àní Ísírẹ́lì kalẹ̀ fún ara rẹ láti sọ wọ́n di ènìyàn rẹ títí láé; ìwọ Olúwa sì wá di Ọlọ́run fún wọn.
Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 7
Wo 2 Sámúẹ́lì 7:24 ni o tọ