2 Sámúẹ́lì 7:25 BMY

25 “Ǹjẹ́, Olúwa Ọlọ́run, jẹ́ kí ọ̀rọ̀ náà tí ìwọ sọ ní ti ìránṣẹ́ rẹ, àti ní ti ìdílé rẹ̀, kí ó dúró títí láé, kí ó sí ṣe bí ìwọ ti wí.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 7

Wo 2 Sámúẹ́lì 7:25 ni o tọ