2 Sámúẹ́lì 9:6 BMY

6 Méfibóṣétì ọmọ Jónátaanì ọmọ Ṣọ́ọ̀lù sì tọ Dáfídì wá, ó sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀, ó sì bú ọlá fún un.Dáfídì sì wí pé, “Méfibóṣétì!”Òun sì dáhún wí pé, “Wò ó, ìránṣẹ́ rẹ!”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 9

Wo 2 Sámúẹ́lì 9:6 ni o tọ