2 Sámúẹ́lì 9:7 BMY

7 Dáfídì sì wí fún un pé, “Má ṣe bẹ̀rù: nítorí pé nítòótọ́ èmi ó ṣe oore fún ọ nítorí Jónátanì baba rẹ, èmi ó sì tún fi gbogbo ilé Ṣọ́ọ̀lù baba rẹ fún ọ: ìwọ ó sì máa bá mi jẹun nígbà gbogbo ní ibi oúnjẹ mi.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 9

Wo 2 Sámúẹ́lì 9:7 ni o tọ