Oníwàásù 1:13 BMY

13 Mo fi àsìkò mi sílẹ̀ láti kọ́ àti láti ṣe àwárí pẹ̀lú ọgbọ́n, gbogbo ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run. Háà ẹrù wúwo tí Ọlọ́run ti gbé lé àwọn ènìyàn:

Ka pipe ipin Oníwàásù 1

Wo Oníwàásù 1:13 ni o tọ