Oníwàásù 8:11 BMY

11 Nígbà tí a kò bá tètè ṣe ìdájọ́ fún ẹlẹ́ṣẹ̀ kíákíá, ọkàn àwọn ènìyàn a máa kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìmọ̀ láti ṣe ibi.

Ka pipe ipin Oníwàásù 8

Wo Oníwàásù 8:11 ni o tọ