Oníwàásù 8:12 BMY

12 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé òsìkà ènìyàn ń ṣe ọgọ́rùn-ún ibi ṣíbẹ̀ tí ó sì wà láàyè fún ìgbà pípẹ́, mo mọ̀ wí pé yóò dára fún ẹni tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Oníwàásù 8

Wo Oníwàásù 8:12 ni o tọ