Lúùkù 1:14 BMY

14 Òun yóò sì jẹ́ ayọ̀ àti ìdùnnú fún ọ: ènìyàn púpọ̀ yóò sì yọ̀ sí ìbí rẹ.

Ka pipe ipin Lúùkù 1

Wo Lúùkù 1:14 ni o tọ