Lúùkù 1:59 BMY

59 Ó sì ṣe, ní ijọ́ kẹjọ wọ́n wá láti kọ ọmọ náà nílà; wọ́n sì fẹ́ sọ orúkọ rẹ̀ ní Sakaráyà, gẹ́gẹ́ bí orúkọ baba rẹ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 1

Wo Lúùkù 1:59 ni o tọ