6 Àwọn méjèèjì sì ṣe olódodo níwájú Ọlọ́run, wọ́n ń rìn ní gbogbo òfin àti ìlànà Olúwa ní àìlẹ́gàn.
Ka pipe ipin Lúùkù 1
Wo Lúùkù 1:6 ni o tọ