Lúùkù 11:16 BMY

16 Àwọn ẹlòmíràn sì ń dán an wò, wọ́n ń fẹ́ àmì lọ́dọ̀ rẹ̀ láti ọ̀run wá.

Ka pipe ipin Lúùkù 11

Wo Lúùkù 11:16 ni o tọ