Lúùkù 11:53 BMY

53 Bí ó ti ń lọ kúrò níbẹ̀, àwọn akọ̀wé àti àwọn Farisí bẹ̀rẹ̀ sí bi í lọ́rọ̀ gidigidi, wọ́n sì ń yọ ọ́ lẹ́nu láti wí nǹkan púpọ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 11

Wo Lúùkù 11:53 ni o tọ