Lúùkù 12:19 BMY

19 Èmi ó sì wí fún ọkàn mi pé, ọkàn, ìwọ ní ọrọ̀ púpọ̀ tí a tò jọ fún ọ̀pọ̀ ọdún; sinmi, máa jẹ, máa mu, má a yọ̀.”

Ka pipe ipin Lúùkù 12

Wo Lúùkù 12:19 ni o tọ