Lúùkù 12:38 BMY

38 Bí olúwa wọn bá sì dé nígbà ìṣọ́ kejì, tàbí tí ó sì dé nígbà ìṣọ́ kẹta, tí ó sì bá wọn bẹ́ẹ̀, ìbùkún ni fún àwọn ọmọ-ọ̀dọ̀ náà.

Ka pipe ipin Lúùkù 12

Wo Lúùkù 12:38 ni o tọ